Oyo Vanguard
Oyo Vanguard Is Oyo Best Political Online Community Newspaper, publishing News On Politics, Culture, Sports And Entertainment.

ADITU IN OYO TOWN: How 100-Years Igi Odan Resurrect After It Fell Down During Rain Fail, Reportedly Killing Four Persons (VIDEO)

519

A 100 years old misterious tree Igi Odan which Reportedly fell down and its branches were chopped off has returned back to it’s normal postures Akéde Ọ̀yọ́ can confirm.

The tree sources said killed four persons during the incident, other reports said no live was lost according to eyewitness in the area, though admitted that someone got injured in the process.

- Advertisement -

Same source said all affected persons are still at the hospital recuperating.

The tree which fell later resurrected and returned to its normal postures, sources said there were no signs that the tree fell at the first instance.

Akéde Ọ̀yọ́ recall that after the tree fell down, concerned residents after many attempts were able to chop the branches of the tree while the bottom was left behind, the branches were reportedly gathered in one corner.

It was a thing of surprise that the following day the tree returned back to it normal postures as if it never fell at the first place, the only difference was the fact that it’s branches were chopped off.

The Alaafin of Oyo His Imperial Majesty Oba Lamidi Adeyemi the 111, paid a visit to the venue, He plead with residents to calm the tension down, while also assuring them that the needful will be done.

In his words in Yoruba

Alaáfin Oyo ti kan sí ìdí igi to wó, ti ará ìlú gé ní àná tó tun díde padà lónìí-

Alaafin Oyo ti de ibi iṣẹlẹ to ṣẹlẹ ni ilu Oyo.Ọjọ́ burúkú èṣù gbomimú ní Ọyọ! igi ńlá wó pa ọ̀pọ̀ ènìyàn

Igi Odan yii ni wọn ni o wo ti o si ṣe ijamba fun awọn eeyan ti wọn si n yọ wọn sita labẹ igi naa.

Nigba naa ni wọn pe awọn agegi lati wa ba wọn ge igi naa lati doola ẹmi awọin eeyan.

Nigba ti ọrọ igi to dide yii n di nkan mii, Alaafin iku Baba Yeye, Adeyemi naa ti kan sibẹ lati ba awọn ara ilu Oyo sọrọ.

Alaafin fi awọn eeyan naa ni ọkan balẹ pe ilu yoo ṣe ohun to yẹ ki iru rẹ ma baa ṣẹlẹ mọ ti yoo maa mu ẹmi awọn eniyan lọ.

Awọn ti iṣẹlẹ naa ṣoju wọn ṣalaye bi wọn ṣe lọ pe ge igi ge igi lati wa ran wọn lọwọ.

Wọn ni pe iyalẹnu lo jẹ fun wọn pe igi naa dide duro pada lonii.

O kere tan eniyan mẹrin lo ba ijamba igi to wo lulẹ lọ lasiko ojo arọrọda ni agbegbe Alafin Sabo Idi Odun ni ipinlẹ Ọyọ.

Iroyin ni ojo arọrọda lo fa ti awọn eniyan to fi mọ ọmọde ati agba ti wọn sa si abẹ igi naa lati duro ki ojo fi da, ki ọlọjọ to de.

Awọn ti iroyin naa ṣoju wọn niawọn ti igi nla naa wọpa yii ni wọn sa fun ojo ti wọn si lọ joko si abẹ igi ọun ti ẹlẹran kan ti ma n ta ẹran labẹ igi nla naa.

SOURCE: AKÉDE Ọ̀YỌ́

Get real time updates directly on you device, subscribe now.

Leave A Reply

Your email address will not be published.

This website uses cookies to improve your experience. We'll assume you're ok with this, but you can opt-out if you wish. Accept Read More